Bibori Awon Idena ati Idiwo si Gbigbo Ohun Olorun

Lati owo Marku ati Patti Virkler

Ati fi aye sile fun tite iwe yi fun enikeni ti oba fe se bee fun titan kale re

Fun opolopo awa olugbe aye ode oni, ise iyanu to tobi julo ni igbesi aye wa ni gbigbo ohun Olorun ni ketekete ati ni gbanba lati igba de igba. Awon Kiristieni ma nse ariyan jiyan larin ara won nipa wipe boya lo tile seese lati gbo ohun Olorun. Lai se ani ani awon to ti nba Olorun foro jomi toro oro mo daju wipe eleyi sese, beeni oma nmu inu awon eniyan bayi dun ati inu Olorun pelu. Nitori idi eyi lase dawa saye, lati le se ijosin fun Olorun ati lati le ma baa soro po pelu Eleda wa. Nitoria, pelu gbigbe owo wa soke sii pelu  opolopo ayo lati nu okan wa wa si inu imole Omo re la se ngba ibasepo pelu re. Ni tooto, Imole Owuro ni ti yo sinu okan wa ati isotele awon oro re wa se kedere siwa (Peteru keji. 1:19)

Nigba miran ewe, ama nri idoju ko ati awon iji ti won nma fe diwa lowo ibasepo wa pelu Baba. Ninu iwe ti an ka bayi, afe so nipa awon iji ati awon ona a le fi doju koo nipa ti agbara Emi mimo ati imo ti awon ilana re

Lakoko, awon ilana ti inu bibeli fun awon ti won ti setan lati sun moo. Eleyi la le se awari re ninu iriri Agbala Itura re. Enikeni to ba fe ri iriri Olorun ni Ibi mimo re julo (lati inu emi wa wa) gbodo ko eko nipa gbi gbe ninu iriri Agbala Itura, Ao wa wo inu odi Agbala Itura re yi pelu iyin ati idupe. Nipa gbigbe aso ododo wo eyi ti Kiristi ti pese sile fun wa. (Orin Davidi 100:4; Isaiah 61: 10).

Ao wa bo siwa ju pepe ti afi ide se, ni ibiti ao fa ara wa sile gege bi ebo aaye, mimo eyi ti Olorun yio se itewo gba. (Awon ara Romu 12:1) Ani lati ma  se eleyi, kise nipa akoko igbala nikan sugbon lati ojumo de ojumo bi ati se nji dide lowuro.

Eleyi ti ote le ti isiwaju ni wipe a o wa si ibi agbada iwenumo ibi yi ao ti we ara wa nipa Oro (Awon ara Ephesu 5: 26). Bi ati se teju wa mo Oro naa, ao wa gba laye lati we igbe aye wa, ati lati we gbogbo ise wa. Nitorina, ilana ti bibeli gbe ka le fun wa lati maa se asaro yio wa di ohun imulo fun wa lati wa siwa ju Olorun.

Nigbayi la o wa bo si ibi mimo, ninu emi ati okan wa, ibi yi ni Olorun maa nba okan wa ati ife ara wa soro. Lakoko ao wa lo si ibi tabili akara ifihan, lori tabili ti awon alufa ti njeun papo. Eleyi ma nse afihan ibasepo pelu Olorun nipa  jijosin papo pelu re. Bi ati se nlo alikama papo lati fi se akara bayi nani Olorun se ma nmu awon ife okan wa lo si inu ero lati le loo kunna ninu ti ibani sepo awa onigbagbo, ao wa ma gbaradi lati ba Olorun rin jinle ninu okan wa.

Siwaju, ao wa duro si iwaju opa fitila ti afi wura se loso, eleyi lo nse ifiwe bi ati se le ko lati ni iwa bi ti Olorun lati oke wa, eyi ti o ma ntan imole nipa lilo ororo, ti oduro gege bi itan san tabi Emi mimo. Ati wipe,bi ati se nse igbeyewo oro Olorun ninu itan san emi mimo yi, isipaya lati oke wa maa nso kale sinu okan wa, ti oma nmu igbe aye otun wa ba eniyan eleyi ti oma nmu jinle nimu Olorun. (Awon ara korinti 3; 18)

Ao wa lo tara si ibi pepe turari aladidun, ni ibiti ati nkeko lati le ma fi igba gbogbo yin ati lati le maa josin fun Olorun oga ogo, oluda aye ati orun. Gege bi oorun adidun eyi ti oma nfi igba gbogbo gun oke to Olorun lo, bayi ni iyin wa ati ijosin wa se maa ngunke wa si iho imu Oluwa. (Orin David 14; 2). Ati kowa bi ati sele je olojosin, lati ipase isipaya nipa imo, ati se awari wipe Oba Oga Ogo maa nfi igba gbogbo joba lori awon ero ngba gbogbo eneiyan, ati kowa bia ati se le maa yin ni ibi gbogbo ati ninu ohun gbogbo (Danieli 4; 10). Ati ko lati maa josin ninu emi ati ni tooto (Johannu 4; 24).  

 

Ibasepo Ojokoroju

Bayi ati wa setan lati gun oke tarata si iwaju Re, bi asi ti se te oju wa mo ogo re ni bi baa soro oju koro ju ati enu de enu pelu Olorun oga ogo. Iru anfani nla wo leyi je! Eleyi ti logo to! Lati duro ni ijosin ni iwaju Olorun orun oun aye tika lara re. Iboju ti wa di fifaya, ona ti sile, lati ipase itaje sile Kiristi Jesu Oluwa ati Olugbala wa (Heb. 10; 19,20) 

Ni ipase eleyi ni Olorun ti se pese ona sile fun wa lati le wole too wa lati le ba Emi mimo josin po. Ona eleyi lati la sile kedere fun wa lati inu Majemu lai lai wa ti osi ti di fifaya fun wa lati le jijo ni asepo ninu Majemu Titun. Bayi ni igba ku gba ti awon iji tabi efufu lile ba ja lati le di wa lowo lati wa si iwaju Oba awon Oba, ale pada sehin lati wa maa tun ona na rin eleyi ti oun tika lara re ti pese sile fun wa. Ao wa bere awon ibere wonyi:

  1. Nje mo nkorin yin, fun aso ododo to gbe womi bi? Nje mo ri ara mi ninu aso yi bi? Nje moti di eniti ati we mo ti nko ni abawon kan kan niwa ju Oba na?

  2. Nje mo ti fi ife ti ara mi sile ninu ohun gbogbo bayi bayi ti mo si ti gbara di lati maa se ife ati ilepa Baba mi ni gbogbo ona.

  3. Nje mo ti di eni ti ati we mo ni gbogbo ojo nipa imulo oro Olorun ni igbesi aye mi?

  4. Nje okan mi kun fun ife si awon to je ti ara Christi lara awon ti mo wa, nje mo npara mo fun awon ara mi ninu Christieni? Nje mo jeki ife mi rele niwaju ara kunrin mi bi?

  5. Nje mo nse agbe yewo oro Olorun lore kore, ti mosi nse aferi Emi mimo, ti mo si nfe ki ifihan lati oke wa tan imole si igbesi aye mi?

  6. Nje emi ama fi igba gbogbo josin? Nje gbogbo ikun sinu ti yera fun ijosin ni igbesi aye mi? nje emi maa nfi igba gbogbo ni ife si ohun to dara, to rewa ati ohun ti odaniloju?

  7. Nje mo duro lati teju mo ifara han ogo Olorun alagbara lati ri gba awon ibani soro lati odo re wa?

Ni igba de igba mo se awari wipe ti mo rin ninu iriri ti Agbala Itura yi, gbogbo idena to ba wun kio wa nigba ti mo ba wa siwa ju Olorun lati gbadura yio poora ni. Bi ko ba ri bee, Olorunti pese ona aba yo ninu iwe Heberu 10; 22:

Eje ki asunmo tosi pelu okan to kun fun isotito ati igbagbo, ki awe okan wa mo kuro ninu etan ati ara wa pelu omi mimo

Ninu ese yi ale ri kokoro merin miran ti ole mu idena kuro ni gigbo ran si Oludari wa.

Kokoro akoko ni wipe agbodo ni okan aise etan, kole si iwa agabagebe ninu wa, ko gbodo si ise iye meji, ko gbodo si aifokan tan. Sugbon gbogbo iwa mimo, ai labawon, ifi gbogbo ara ji gege bi omo kekere ti se maa nfe lati se ife ti Olorun.

Fun afikun, a gbodo ni igbagbo to daju, ni ona miran ako le se iyemeji si orisun omi iye ti onsan lati inu okan wa wa. A gbodo mo daju wipe awon okan to nje jadelati inu okan wa ni igbati anse aferi oju Olorun ninu adura je ona ti Olorun ngba lati bawa soro (Johanu 1; 38,39). Ti ako ba ni igbabo ti odaju, ti aba wa se iye meji, oun je Imanueli eyi otumo si wipe Olorun wa pelu wa, nipa sise eleyi ao wa muu kio yera fun wa nipa  Emi re

Nitori idi eyi a gbodo ni igbagbo wipe Oun ni eni ti oma nbukun fun awon ti won maa nfi gvbogbo okan won wa oju re, ti won nmaa nfi igbagbo ri gba nipa imisi Olorun ninu okan won wa. Ki a maa fi igbagbo ni igbokan le wipe lo tito ni Emi Olorun nba ni soro (Heberu 11; 6). Aima je bee, esin Kiristieni je iro patapata. Laise ani ani, emi mo wipe otito ni.

Ona keta ti atun le gba woo ni wipe, oye fun wa ki okan wa di wiwe mo kuro ninu gbogbo iwa aimo, ti aba se awari ese ni igbesi aye wa nse lo ye fun wa lati wa si abe isan eje Christi ki awa se imukuro ese kuro lara wa gege bi ila oorun ti se jina to si iwo oorun (Orin Davidi 103; 12). Lehin eleyi awa gbagbe nipa iru ese bee gege bi gbogbo okan wa se dari si odo Eleda wa. Gbogbo aiba le okan la gbodo mu wa si abe iwe nu mo iso di mimo eje Christi fun imu kuro. Nigbana ni okan wa yio wa ri aye lati maa gun oke to Olorun lo.

Ni ipari, a gbodo we wa nipa isi paya oro Olorun, tabi nipa ohun Olorun ( Efesu 5; 26). Awon nkan won ni ti Olorun nba wa so lagbodo ma mulo, aima je be agbara ati le ma ba Olorun rin yio wa fi idi jale.

In igba ti mo ba to Olorun lo ninu adura, emi ama bere nipa wiwa ni ai po ruru okan ni iwaju re. Ma wa maa fi oju woo gege bi oti se wa pelu mi, ma wa ma reti orisun imisi re (eleyi je ero okan ti on je jade lai rotele wa), ma wa bere si se akosile awon ero okan mi wonyi gege bi oti se nje jade sinu okan mi, (Ale se awari eleyi ninu iwe Habakuku 2; 1,2.) Ti mo ba wa ri ihamo kan ti ofe dimi lowo lati gbo ohun ti Olorun nba mi so ati lati le ri iran re. Ma wa se agbeyewo awon ibere ti a bere siwaju nipa igbesi aye inu Agbala Itura. Fun opolopo igba ti mo ba se iru agbeyewo eleyi , ni mo ma nse awari iru idiwo bee ni kete na ni uno ti muwon kuro. Ti idena yi ba wa sibe, ma wa bere ibere merin ti owa ninu iwe  Heberu 10; 22 pe nje okan mi wa ni pipe, to si se ododo ati wipe! boya ni tooto ni mo je Olufokan sin? Nje mo ti jowo ara mi sile patapata fun Olorun bi mo se ntoo lo bi? Nje mo ni idani loju igbagbo wipe oun wa pelu mi ati wipe oun gbe inu okan mi (ti oro mo Emi oun pelu Korinti kini 6; 17)? Ni afi kun, mo gbodo bere boya mo gboran sii awon oro isiwaju ti oti bami so.

Awon ilana meji, iriri ti Agbala Itura, ati ififi okan ma se iwadi ohun ti ako sinu iwe Heberu 10; 22, (ti aba wa lo pelu apere ti iwe Habakuku 2; 1,2) yio fun wa ni aye ni igba gbogbo fun opolopo wa ki aba le gbo daju ohun Olorun lati inu okan wa wa kia asi se akosile awon ero okan wa eyi ti oun je jade lati okan, iran ati ife eyi ti oma nje jade ninu okan wa bi atise nse awari oju Olorun. Nipa eleyi opolopo awon idena si gbigbo ohun Olorun ni yio di mimu kuro ti aba ti le tele awon ilana bibeli won yi.

Ni kete ti aba ti bere si se akosile awon ero okan wa wonyi, osese fun wa lati maa ri awon asise die die, tabi awon ti odabi awon asise ninu awon akosile wa. Iru eleyi le waye li opolopo ona, uno so die fun wa ona abayo.

Okan lara awon isoro wa ni wipe, ni igba ti aba ngbadura nse ni ama nteju mo ohun ti angbadura nipa re, dipo wipe ki a teju  wa mo Jesu. Eni ti nse ibere ati olupari igbagbo wa. Nitorina idahun maa nwa ninu ohun ti angbadura nipa re dipo pe ki idahun wa lati odo Olorun. Ona aba yo si iru eleyi ni wipe, oye kia kiye sara lati te oju wa mo Jesu (Heberu 12;2) dipo ohun kan kan miran, tabi eniyan, tabi ise kan. Ti aba mu eniyan tabi ise kan wa si waju Olorun ninu adura, nse loye ki a ri wipe a gbee kale niwaju re, ki awa maa se akiyesi boya yio soro tabi ohun ti yio se nipa nkan nna. Nigbayi ni ero ti on jade si wa lokan yio je eyi tii se mimo.

 

Iduro sinsin

Ona keji ni wipe lare awon ase Olorun ni wipe ti Olorun ba pase nkankan lati se tabi lati lo, kii se wipe ofe ki eniyan se iru nkan bee, sugbon onse bayi lati le fi wa si ibikan pato ti on fe lati pade wa tabi lati le dari wa nipa sise tan lati se iru ife re. Apere eleyi la o ri ninu iwe Genesisi 22, nigbati Olorun so fun Abrahamu kio ofi omo re ru ebo si oun. Sugbon bi Abrahamu ti bere si se igboran si ase re yi Olorun yii pada, owa nso fun wipe ki oma se fi omo re ru ebo mo. Bayi se ale wa so wipe oro ti Olorun koko baa so je esi? Rara, Olorun kan nfe ki Abrahamu de ibiti yio ti gba isise si ipinu Olorun fun igbesi aye re. Ni kete ti oti se eleyi Olorun wa yi ase re pada lojiji pelu ase titun miran. Eleyi maa nsele simi lopolopo igba ninu akosile mi. Opolopo ase bayi maa nwaye ni igbati Olorun ba fe mu eniyan kan wa si ibiti yio tun ti dari re si ibo miran fun mi ati fun awon elo miran.

Ona keta ti opari re, awon asise miran ti a ma so nipa re je awon asise ki eniyan maa fi igba bo ogbun ninu. Ororun fun eniyan lati tumo oro ti o ko sile wipe oje bayi tabi bayi, kaka ki oni tohun ri gege bi oti se ri gele. Opolopo igba, bi mo ba pada lo sinu awon ohun ti mo ti se akosile won ti mo wa nro wipe awon nkan ti mo ko wonyi je esi, ama je ohun iya lenu fun mi bi awon ohun to mo sile wonyi ba wa si imuse. Nkan ti emi nfi okan mi ro pe won je ko ni won je. Ejeki aso ra lati gbo ohun ti Oluwa nba wa so.

(Ikokan awon koko oro ti ati ko wonyi ni ase alaye re le kun rere ni iwe meji otooto lati owo Marku ati Patti Virkler: Iforo jomi toro oro pelu Olorun ati Edeyede pelu Olorun 

ti owa la rowo to lati odo Communion with God Ministries, 3792 Broadway St., Cheektowaga, NY 14227. Phone: 716-681-4896; Fax: 716-685-3908; Website: www.cwgministries.org)

Edi alabu kun fun.

Results

Results 21 - 30 of 485

Pages

Conversation Starters with God 2

Just the Questions! By Gloria Gierach | 120 Pages | Retail $14.99

What better way to converse with God than to have great questions that improve that communication? 375 relationship-building questions between you and God.

Price: $14.99

Conversation Starters with God Journal

By Gloria Gierach | 406 Pages | Retail $24.99

What better way to converse with God than to have great questions that improve that communication?   Each page of this workbook has a powerful question on the top followed by a blank page to journal out your dialogue with God.

Price: $24.99
Corporate Communion with God

Corporate Communion with God

by Mark and Patti Virkler | 35 Pages

Bring the principles of how to hear God's voice to your prayer meetings with the ideas recommended in this guide. As your prayer group encounters the spirit world, there are no limits to where God may wish to take you. He may fill your hearts with visions and burdens of needs half-way around the world. He may take you into the heavenlies to reveal the activity of spiritual forces surrounding you. He may reveal to you a vision of His future purposes and draw you into calling them forth. The possibilities are as limitless and varied as is the Spirit of God.

Price: $4.95

Decoding Deception Workbook

by Mark Virkler

This 40-page workbook provides you copies of 113 PowerPoint utilized in the Decoding Deception training. Spaces for you to take notes are available next to each PowerPoint. If receiving training in a group, we highly recommend that EVERY member of the group have their own copy. It offers you the following four benefits:

Price: $5.95
Eden's Health Plan - Go Natural!

Eden's Health Plan - Go Natural!

by Mark and Patti Virkler | 289 Pages

Discover how you can take charge of your own health — keeping yourself young, energetic, attractive, and free of degenerative diseases! Discover the biblical injunctions on diet and health, and the amazing correlations between them and modern scientific research.

Price: $19.95

EFT for Christians: 52 Tapping Devotions

by Sherrie Rice Smith, R.N. (Retired)

"The amazing versatility of God’s gift of EFT stands out in this fourth installment in the EFT for Christians series. Sherrie Rice Smith’s latest book EFT for Christians – 52 Tapping Devotions helps believers incorporate Emotional Freedom Techniques into their everyday lives. In these weekly devotionals Sherrie clearly demonstrates how to connect Scripture and tapping in a practical way. Don’t just read this book; apply the principles and release God’s healing power in your life today."

Price: $15.00
EFT for Christians

Emotional Freedom Techniques - EFT for Christians: Tapping Into God's Peace and Joy

by Charity Virkler Kayembe and Sherrie Rice Smith | 208 Pages | Published 2016

Scripture tells us that we comfort others with the comfort we ourselves have received (2 Corinthians 1:3–5). To the degree that we are healed and comforted, we can offer those same gifts much more freely to others

Price: $15.99

End-Times Prophecy

by Timothy Paul Jones, PhD | 364 p. | c2011

This is an outstanding book, which clearly and simply lays out four differing views of end time prophecy, providing scriptural support for each, showing the unique approaches each view takes, and encouraging you to understand and not judge those who disagree with you. Finally we can honor and love all people (1 Pet. 2:17) as we consider various views of interpreting end time prophecy. What a gift to the body of Christ. Thank you, Timothy Paul Jones!!!

Price: $19.95
Experiencing God Together

Experiencing God Together

by Mark and Patti Virkler | 105 Pages

This book explains how to turn small group meetings into times of dynamic sharing of revelation concerning the real life issues we face daily. It addresses how to get everyone involved, how to limit the naturally talkative, and how to keep things on track.

Price: $12.95
Flow of Life

Flow of Life

by Mark and Patti Virkler | 102 Pages

This book guides you in doing original research in any area in which you are seeking the supernatural release of divine power through your life. For example, one sample project recorded in this book is entitled, "Healing a Chronic Illness Through Receiving and Acting Upon a Word of Knowledge." 

Price: $12.95

Pages